TRACT MINISTRY
THIS TRACT MINISTRY IS A WORD OF GOD THAT SHARING TO EVERYBODY TO BE READ AND HAVE LIFE CHANGING i.e FROM BAD LIFE TO GOOD LIFE
Translate
Thursday 11 April 2013
“Nitoriti nwon a ma wi, Sugbon won kiise”.
“Sugbon e ma se gege bi ise won: nitori nwon a ma wi sugbon nwon kiise”Mathew 23:3.Iru awon eniyan bayi po ninu ijo loni eyi gan ni a npe ni “Agabagebe”,nitori idi eyi gbogbo eko ati awon oro Olorun tiwo- n ngbo koni-tumo si won rara. Won pe ara won ni Juu{Jews}nitooto won je Sinago- gu Esu, niti eko won mo nipa re daradara, Sugbon won kuna lati le fi eko ti won nko si ise. Akoko niyi o lati ni emi bii ti Woli Esra ninu aye wa, paapaa julo ninu ijo wa “Nitori Esra ti mura tan li okan re lati ma wa ofin Oluwa, ati lati see,ati lati ma koni li ofin ati idajo ni Isreali”Esra 7:10. Mo fe ki egbe otito yi yewo gegebi olori,oludari, olusoaguntan,omoleyin,oludasile ati awon alafenu je Kristeni. Ki o yipada ninu iwa buburu re, e je ki a je apere rere fun awon ti a n ko ni oro Olorun, ka si tun je ki oro wa ati eko wa wa ni ibamu pelu Bibeli. Bibeli wipe “Ninu ohun gbogbo e fi ara yin han gegebi apere rere, ninu eko fi ara re han bi alaidibaje”Aposteli Paulu lo n gba Titu niyanju.Paulu ti gbo nipa awon eleko-eke, o tun so fun Titu pe o gbodo gbiyanju lati ko eko ti o ye koro ati awon eko ti o wa ni ibamu pelu oro Olorun yato si ogbon ori eniyan, ki awon agba okun- rin je eni iwontunwosi, eni-owo,alairekoja, eniti o ye kooro nigbagbo, ni ife, ni suru. Bee gege ni ki awon agba obinrin je enio-wo ni iwa, ki nwon ma je asoro-eni-lehin tabi omuti, bikose olukoni ni ohun rere, ki won ki o le to awon odomobinrin lati feran awon oko won, lati feran awon omo won, lati je alairekoja, mimo, osise nile, eni rere, awon ti nteriba fun awon oko won, ki oro Olorun ki o mase di isoro-odi si, ninu ohun gbogbo maa fi ara re han li apere ise rere, ninu eko maa fi aisebaje han, iwa agba,Titu 2:1-8; loni awon alafenu je Kristeni po ninu aye, “Jesu wi fun ijo enia ati awon omoehin re pe, awon akowe pelu awon Farisi joko ni ipo Mose! Nitorina ohunkohun gbogbo ti won ba wipe ki e kiyesi, e maa kiyesi won
ki e si maa se won, sugbon e maa se gegebi ise won: nitoriti nwon a ma wi, sugbon nwon ki ise. Nitori nwon a di eru wuwo ti o si soro lati ru, nwon a si gbee ka awon enia li ejika, sugbon awon tikarawon ko je fi ika won kan eru naa, Mathew 23:1 - 4. Loni awon eniyan ma nfe ipo giga lawujo, igba- gbo tiwon ni ti ipo giga, tabi ohunkohun ti o ba ma na won lati gbaa tabi raa pa patapa ta, tabi bi oba la emi lo won yio pa eniyan bee lona ati de iru ipo. Sugbon gbogbo ise won ni won ma nse tori ki eniyan le ri won.. won nfe ipo ola nibi ase, ati ibujoko ola ni Sinagogu, ati ikini li oja ati ki enia maa pe won pe Rabbi,Rabbi,{oluko} pelu gbogbo nkan wonyi Olorun nfe iwa irele, E ma si se pe enikan ni Baba nyin li aye, nitori enikan ni Baba eniti mbe li orun. Ki a ma si se pe yin ni Olukoni nitori okan li Olu- koni yin, ani Kristi. Sugbon eniti o ba poju ninu nyin, On ni yio je iranse nyin, Enikeni ti o ba si gbe ara re ga li a o re sile, Enikeni ti o ba re ara re sile li a o gbe ga.{ese 8-12} Nitori eyi Olorun binu si igbe aye agabage- be “Egbe ni fun nyin, eyin akowe ati Farisi, agabagebe: nitori enyin je ile awon opo run ati nitori asehan, e ngbadura gigun: nitoriti enyin tikarayin ko wole beli enyin ko je ki awon ti nwole ki o wole. Je kin so fun yin pelu idaniloju pe awon eniyan wonyi je okuta idigbolu fun elomiran , paapaa julo awon ti o fe gba Ihinrere ti Jesu gbo.Won tile tun mo nipa eko daradara ti won ko ni telee, eyi lo fa ti Jesu se fi won bu{curse} “Egbe ni fun nyin eyin amona afoju, ti o n wipe Enikeni ti o ba fi Tempili bura, kosi nkan, Sugbon Enikeni ti o ba fi Wura, tabi Tempili ti nso Wura di mimo? ese13- 24; Nje eyin ti e wa ninu Egbe Oni-mo-tara-enikan? , “Egbe ni fun nyin, enyin akowe ati Farisi, agabagebe: nitori enyin nfo ode ago ati awopoko mo, sugbon inu won kun fun ireje ati wobia. Iwo afoju Farisi, teeko fo eyi ti mbe ninu ago ati awopoko mo na, ki ode won ki o le mo pelu.Egbe ni fun yin, enyin akowe ati Farisi, agabagebe: nitoriti enyin dabi iboji funfun, ti o dara li ode, sugbon ninu nwon kun fun egungun oku, ati fun egbin gbogbo. Gege bee li enyin pelu farahan li ode bi olododo fun enia, sugbon ninu, e kun fun agabagebe ati ese , ese 25- 33”. Eko dara- dara o dara nitooto, sugbon eko ti ko ba wa ni ibamu pelu oro Olorun o le yori si iyapa larin eniyan ati Olorun tabi iku ayeraye,Sugb- on EMI OLORUN ni nfun ni IYE lopolo- po, nitori idi eyi fi ara re sile fun Olorun {jowo ara re fun Olorun}ati fun EMI re lati maa dari igbe aye re lati se IFE Re. Mase dake nitori ailera re tabi eru aikun- oju-osuwon lati wasu, gbiyanju lati maa ka Oro Olorun{Bibeli} tabi ki o se gegebi ase re si O .Soo ki o si see, Olorun Alafia yio wa pelu yin bi e ti nka iwe yi.
Ni ipari ohunkohun ti ise ooto,ohunkohun ti ise owo,ohunkohun ti se tito, ohunkohun ti o ni irohin rere: bi iwa tito kan ba wa,.... E maa gba nkan wonyi ro.... E maa se won; Olorun alafia yio wa pelu yin, {AMIN}.
Fun alaye sii, ibere, amoran,ebe adura, Eri Yin, tabi e n fe iwe yi sii, kowe si :-
ReviveThe Whole World For Christ.
P.O.Box 1736,
Osogbo, Osun State. Nigeria.
TI OLORUN BA FI SI O LO KAN LATI RAN ILE-ISE IWE YI LOWO SEE LONI OLA LEE PE JU, KOSI IYE OWO TI O KERE JU LATI FI SILE TABI TI O POJU, KI ORO OLORUN LE MAA GBINLE SII.
NJE O N SIYEMEJI NIPA JESU.
E je kin fi asiko yi so fun yin pe ipa meji ni eniyan pin si,Okunrin tabi Obinrin, Eniyan kole sai yan okan ninu nkan meji yi, ninu ki o sonu tabi ki a gbaala, eyiti o tumo sipe Esu tabi Olo- run ni oga re,Kini e ro wipe o fa iyapa larin eniyan ati Olorun,eyo oro meta ni ESE {SIN} “1Johanu 3:4 wipe Enikeni ti o ba ndese o uru ofin pelu, nitori ese ni riru ofin” E je ki a tun kaa siwaju 1johanu3:8 Eniti o ba ndese ti Esu ni nitori ni atete kose ni esu ti n dese nito- ri eyini Omo Olorun se farahan ki o le pa ise esu run. je ki otito yi ki o ye o wipe gbogbo eniyan ti a bi nipase Okun rin akoko “Adamu” ati Obinrin akoko “Efa” {nipa ibasepo Okunrin ati Obin- rin elese ni} Awa naa gbodo pa ise-Esu run ninu aye wa, Niwon igbati nko ti ni anfani lati wa lodo yin ni loo-loo yi Ey-in gan ni onidajo arayin nipase Oro Olo run, Jesu wipe nipa eso won la o fi mo won. Bi iwo naa ti mo iyato ti o wa lar- in igi eleso;mango ati ibepe, agbado ati oka-baba.Eyi nse apere boya a so eso to dara tabi buburu ninu aye ti a wa lowo yi. Fun apere gbogbo eniyan lomo pe ko dara lati jale gegebi ofin orileede ti laa kale fun wa,eyiti o tumosi wipe ti a ba ri enikan ti o fe lo jale iru eni bee yio ko gbogbo nkan ija lowo ni lati dabobo ara re fun ise ti o fe se yala ni osan gangan tabi ni oru oganjo,Sugbon ti owo palaba re ba lo segi{if he\she is caught} ti owo awon agbofinro ba lo te tabi O.P.C .tabi awon ajo miran tiwon ngbo gun ti iwa ibaje lawujo, atimo wipe iru eni bee ko le lo lai jiya fun iru ese ti o ba da labe ofin, bee ni BIBELI so gbogbo nkan ti o je ese fun wa lai fepo-boyo rara. Je kin so fun yin pe ti e ba ntesiwa ju pelu iwa buburu bayi Esu gan ni oludari iru eniyan bee “Eyin ko mo pe awon alaisoto ki yio jogun ijoba Olorun ? ki a ma tan yin je, ki ise awon agbere, aborisa,awon pansaga, awon olojukoko ro, awon omuti, awon elegan, awon aloni-lowo-gba ni yio jogun ijoba Olorun 1Korinti 6:9-10”. Ti o ba nse okan ninu gbogbo nkan wonyi tabi eyi ti o n se ti emi inu re n ta ko o{eri-okan} Ore mi tooto ki lo de ti o se fi ese sile tabi ki o kunle lori eekun re ki o jewo iru ese bee, ki o si koo sile,nipase oruko kan soso ti a le fi gba eniyan la{JESU} “Sugbon bi awa ba nrin ninu imole, bi o n ti mbe ninu imo- le, awa ni idapo pelu ara wa, eje Jesu Kristi omo re ni nwe wa nu kuro ninu ese gbogbo 1Johanu1:7 ”. “Pe, bi iwo ba fi enu re jewo Jesu loluwa, ti iwo si gbagbo lokan re pe Olorun jii dide kuro ninu oku a o gba o la Romu 10:9” “Sugbon lai si igbagbo ko see se lati wu, nitori eniti o ba nto Olorun wa ko le sai gbagbo pe o onu be, ati pe onu ni olusesan fun awon ti o fi arabale waa,iwe Heberu 11:6”.Kin se awon to ti tori owo wa Olorun, Kin se awon to ti tori Omo waa tabi kin se awon to ti tori Ile wa Olorun, tabi tori Ile wa Olorun {Land], tabi awon to ti tori Onje wa Olorun,tabi tori Moto wa Olorun,tabi nkan aye yi ti yio dibaje lojo kan ti won tori re wa Olorun, Sugbon awon to ti tori igbala -okan won wa Olorun. Awon wonyi ni bibeli sope awon ti o fi ara ba le waa. Nigbti o ba se eyi ni Olorun yio wa fun o ni idasile kuro lowo agbara okunkun, leyin eyi iwo naa a le seso rere. “ Nitori na bi enikeni ba wa ninu Jesu o ti di eda titun, ohun atijo ti koja lo {iwa ole, ija, agbere, pansaga, iro-pipa,ikorira..} Ni tooto ohun gbogbo yio dotun”2 Korinti 5:17.” “Nipa eyi ni gbogbo enia yio fi mo pe omo-ehin ni enyin ise, nigbati enyin ba ni ife si omonikeji nyin, Johanu 13:35”. Je kin so fun yin nipa sise awon nkan wonyi lati maa ka Bibeli re,lati maa gbo ORO- OLORUN ti o ye koro, ati lati ma paa- mo, Ki o si ma lepa ati se awari Otito kan funrare tabi ju bee lo ninu Bibeli re,Iwo na ti deda- tuntun {ATUNBI} niyen jowo gbadura yi pelu mi “Jesu Oluwa mo pe o sinu okan mi, mo si fe ki o ma bami gbe titi, gege bi Oro Olo- run ti wipe, ti enikan ba gbohun re ti o silekun okan re sile Emi(JESU) yio wole, Emi yio si ma ba jeun.‘biko se pe e ba ronupinwada e o segbe bee gege’, Oluwa, kin maa ba segbe, Oluwa gba mi la-gba-tan kin ba le joba pelu re ni- keyin, ni oruko Jesu Oluwa wa,AMIN. Nipari, Oluwa fun mi ni ogbon ati oye lati maa se ife tire nikan laelae, mase gba Esu laye lati da mi pada sinu awon ese ti mo ti jewo ti mo si ti ko sile titi aye mi {AMIN}.
Fun alaye sii, Ibere, Amoran, Ebe adura,Eri Yin, tabi E n fe iwe yi sii kowe si :-
Pastor J.A.Adewumi Configay.
ReviveThe Whole World For Christ.
P.O.Box 1736,
Osogbo, Osun State. Nigeria.
TI OLORUN BA FI SI O LO KAN LATI RAN ILE-ISE IWE YI LOWO SEE LONI OLA LEE PE JU, KOSI IYE OWO TI O KERE JU LATI FI SILE TABI TI O POJU, KI ORO OLORUN LE MAA GBINLE SII.
RU EBUN OLORUN NINU RE SOKE.
“Nitori idi eyi ni mo se nran o leti pe ki iwo ki o maa ru ebun Olorun soke eyiti mbe ninu re nipa gbigbe owo mi le o. Nitoripe Olorun ko fun wa ni emi iberu: bikose ti agbara,ati ti ife,ati ti inu ti o ye koro.Nitorina mase tiju eri Oluwa wa, tabi emi onde re: sugbon ki iwo ki o se alabapin ninu iponju ihinrere gege bi agbara Olorun; Eniti o gbawa la, ti o si fi ipe mimo pe wa, ki ise gege bi ise wa, sugbon gege bi ipinnu ati ore-ofe tire, ti a fifun wa ninu Kristi Jesu lati ayeraye. Sugbon ti a fihan nisisiyi nipa ifarahan Jesu Kristi Olugbala wa, eniti o pa iku re, ti o si mu iye ati aidibaje wa si imole nipase ihinrere,fun eyiti a yan mi se oniwasu ati aposteli ati oluko. Nitori idi eyiti emi se njiya wonyi pelu: sugbon oju ko ti mi: nitori emi mo eniti emi gbagbo, o si da mi loju pe, on le pa ohun ti mo fi lee lowo mo titi di ojo ni. Di apere awon oro ti o ye koro ti iwo ti gbo lodo mi mu, ninu igbagbo ati ife ti mbe ninu Kristi Jesu” 2Timoteu 1:6-13; Mo se atenumo ese kefa “Nitori idi eyi ni mo se nran o leti pe ki iwo ki o maa ru ebun Olorun soke eyiti mbe ninu re nipa gbigbe owo mi le o” Paulu{Paul} kowe yi si arakunrin re Timoteu, o so pe Timoteu ti a ti gbala, Iwo ti o ti ni Emimimo Olorun ti o ngbe ninu re, ti Olorun tun pe lati je okan lara awon iranse re, ti mo si ni anfani lati fi owo mi le o lori gege bi iwon igbagbo ti mo ni lati odo Olorun nitori idi eyi, timoteu ru ebun Olorun soke ninu re ki o si se ohun ti Olorun nbere lowo re. Awon mejeji gbagbo ninu oro Olorun, won gbagbo ninu Olorun kan naa, awon mejeji ni o ti ni igbala okan, ati ipe Olorun ninu aye won, Paulu wa n gbaniyanju lati ru ebun Olorun soke ninu aye re, ninu iwe kini ati ekeji Timoteu, Paulu n tesiwaju lati gba arakunrin re niyanju lati farada inira gege bi omo ogun Kristi, ki o si tun gbiyanju lati fara re se apere iranse Olorun Alaye, ohun ti Paulu se yi lo ye ki gbogbo
wa naa se, nigbati a ko ba ru ebun elomiran soke, ninu eyi gbogbo wa lo fee kuna {fail}, Adupe pe awon die n sa gbogbo ipa ti Olorun fun won lati ru ebun elomiran soke, niwon igbati a ba nwasu ni gbogbo igba ti a ko ri enikan tabi opolopo eniyan lati dide ki won se nkan ti Olorun bere lowo won, mo eyi daju pe a ko i ti sise kankan. Paulu nse eyi lorekore lati le je ki enikan tabi opolopo eniyan gbo ihinrere nipase re, ati lati je ki won se nkan ti Olorun bere lowo won. Paulu, ninu igbiyaju re gan lo mu ki o kowe si awon ijo kan{Romu,Korinti,Fillipi ati bee bee lo}. Se e kuku mo pe awa eniyan a kii fe nkan ti o le ru igbagbo wa soke. Eyi ti yio te opolopo eniyan lorun ju ni ki a maa gbo itan asan ninu ile ijosin bi{alo ijapa,itan ilu oyinbo, ki elomiran bere itan re ni America ki o pari re si Toronto}tabi itan ojo ti won da ijo sile, itan ojo ti o ti wa ninu ijo,{ti ko si idagbasoke kankan ninu aye nipa temi ati tara}.Awon eniyan tile ma n fe ni gbogbo igba ki a sa maa fi oro Olorun boo lai tile nani ati fi oro Olorun bo elomiran. Ki o ko won tan ki won lo jeun lai tile nani lati yewo funrawon lati se awari otito miran funrawon, lati se nkan ti Olorun nfe a gbodo ru ebun Olorun soke ninu aye wa, Mose gan ni iru emi yi lokan re nigbati o so pe “Eyin eniyan e sora e mase gbagbe Olorun” Deuteronomy 6:12. O gbiyanju lati ru ebun Olorun ti o wa laye won soke. Awa naa gbodo mura lati ru ebun tiwa ati telomiran naa soke, boya a fe tabi a ko fe,awon ojogbon ninu imo naa gbodo setan lati ru ebun Olorun soke ninu aye tiwon bakan na. Nje e je mo wipe awon nkan ti o ye ki o maa ru ebun wa soke ti n sele lowolowo bayi, paapaa julo awon nkan ti a nri loni ti o n sele ngbiyanju lati ya okan wa pelu Jesu ni, bii awon eto kan lori ero-amohun-maworan{TV program},Radio, ati kaseti ti n fi ihoho eniyan han{cassette}, enikan tile so nigbakan pe ko si OLORUN, eyiti Bibeli funrare ti fun ni idahun “asiwere eniyan wipe OLORUN kosi” Psalm 14:1.Ohun wonyi n gbiyanju lati so fun wa pe ko si igbala Okan, kosi si Olorun nibi kankan, nigbati a ba de orun lato maa mo eniti Olorun yio gbala fun ra re. Mo roo jowo mase gba eko odi wonyi gbo rara.Awon miran tile nroo wipe ko si nkan ti o kan wa boya enikan lo sorun apadi tabi orun rere, gege bi omo Olorun eyi gbodo kan wa, lati so fun elomiran nkan ti Olorun n bere lowo re.Ki a yera fun nkan ti ara eni- nikan “Nitori gbogbo won ni n toju nkan ti ara won, ki ise nkan ti ise ti Jesu Kristi” Filippi 2:21.Ki se gbogbo wa lo n fe ki elomiran yipada ninu iwa ibi ti o n wu, iwa anikanjopon po lowo awa eniyan{SELFISHNESS}, ti ko ba je bee o ye ki gbogbo wa gbiyanju lati soro Olorun fun enikan tabi opolopo eniyan. Baba dakun ru wa soke lati ronu- piwada ese wa lai ka ipo tabi ola si nkankan. Looto o le maa so pe, se bi tele nko sin Olorun kankan ti mo si de ipo to ga julo nibi ise mi tabi nibi okun owo mi tabi ninu ilu ti mo wa tabi ninu ile eko mi ati beebee lo, bayi e wa nso fun mi pe Olorun kan wa nibikan. Je kin so fun o pe ‘emi alabosi to gun,ti kosi setan lati ronupiwada ojo iya re lo n sun siwaju’ gbo ohun ti bibeli wi “emi n yo nisisiyi,ki ise nitori ti a mu inu yin baje, sugbon nitori ti a mu inu yin baje si ironupiwada; nitoriti a mu yin baje bi eni iwabi-Olorun, ki eyin ki o mase tipase wa padanu li ohunkohun” 2 Korinti 7:9. Loni a maa nwasu gidi gan nipa nkan ti ara ju nkan ti Olorun lo; bii iwasu ona lati di oloro ojiji, igbati elomiran lo si ilu oyinbo tabi ki a gberawa kale bi eniti o n se ise iyanu fun eniyan,enikan tile sope ohun ni oludasile iwasu ona lati di OLORO. Ko tile woopo loni ki iwasu wa duro lori IGBALA - OKAN igbala okan yi lati odo Olorun ni eyi ti n wa kin se nkan ti eniyan le fun eniyan bii tire, ipa eyiti o kan wa nibe ni lati so oro Olorun ti oye kooro funun lati jeki o mo pe gbogbo eniyan ti a bi nipa ibasepo okunrin ati obinrin elese ni, nipa bayi nko a nilo OLUGBALA ti yio gba wa la kuro ninu ese wa gbogbo. Ju gbogo re lo jeki okan re gba ebun OLORUN sinu aye re, jeki ero re da lori nkan ti n se ti OLORUN ju ti ara lo, korira ese ati awon iwa ibi miran, ki o si feran omo enikeji re gege bi ara re , mase tesiwaju ati maa dese sii “awon kan wipe ti won ba da ese daadaa ti Oorun ba fe se idajo yio ri wipe ese won ti poju yio wa fi ibinu ju won sonu nipa bayi nko? awon yio bo sibe iye dipo kiwon wo inu ina orun apadi , mo eyi daju loni pe, eniyan lo rorun fun daadaa lati gbe ebi fun alare tabi ki o sa sise [mistake] sugbon OLORUN ti mo gbagbo kole sa sise rara, nitori idi eyi nko? pa iru ero bee re lokan re ki o gba JESU lolugbala re”, Feran oro Olorun lati maa ka, Feran Kristi gege bi o ti feran re.
Ni ipari OLORUN alafia yio wa pelu gbogbo yin bi e ti nka iwe yi loo{AMIN}.
Fun alaye sii, ibere, amoran, ebe adura,Eri- Yin, tabi E n fe iwe yi sii, kowe si :-
ReviveThe Whole World For Christ.
P.O.Box 1736,
Osogbo, Osun State. Nigeria.
TI OLORUN BA FI SI O LO KAN LATI RAN ILE-ISE IWE YI LOWO SEE LONI OLA LEE PE JU, KOSI IYE OWO TI O KERE JU LATI FI SILE TABI TI O POJU, KI ORO OLORUN LE MAA GBINLE SII.
EGUN KIN WA LAINIDI.
Kini a n pe ni egun? Bawo ni egun se n wonu aye eniyan?ati pe ona melo ni egun gba nwonu aye eniyan?. Egun maa nwonu aye eniyan nipa Aikiyesara, die ree ninu ona ti egun ngba wonu aye eniyan :- (i) Egun lati odo Olorun sori eniyan.(ii)Egun lati odo awon Obi si awon omo. (iii) Egun lati odo iranse Olorun si Omo ijo re. (iv) Egun ajogun ba ninu idile ti a ti bi wa. (v) Egun lati odo ore, oko tabi iyawo.Iwe Atumo Ede Pe Egun Ni :- ipe lati ran emi Esu tabi ibi sori eniyan tabi nkan miran ati bebe lo{e.t.c}.Egun maa nso eniyan di alaimose loju elegbe re tabi loju awon tin reti ki o mu nkan bo wa fun won ti eni naa ko si le se bee . Bibeli so pe .....Tani oni ogbe lainidi.... ‘‘iwe owe23 :29’’.Idi kan pataki gbodo wa fun egun ti o wa ninu aye eniyan, yala ki o je pe won fi se itore anu fun tabi ki o je ti idile ti won, tabi eyi ti a fi owo ara wa fa fun ara wa {egun afowofa}. je kin sare ran yin leti fimu{film} Ogun -Atile wa eyi ti awon Mount Zion se, fun gbogbo eniyan ki a le maa fi se odiwon igbe aye wa , lati mo iru ogun ti o n laa koja yala latile wa ni tabi ajogunba,se bi eranti eniti oga agba ilese pe ki o je oga agba ti eka tilu oyinbo,se bi eranti pe bo se de ibe tan loti so pe ohun o fe gbo nipa esin ti Kristi bi o ti wu ki o mo, eyi losokunfa bi o se da Oludari eto isin won duro {FELLOWSHIP LEADER} lenu ise oojo re, ti o si je pe ogun atilewa lo n ja , ipo ti ohun bo si lohun yen enikan lo wona ati debe sugbon ti ori tire takoo, se e ko gba- gbe pe o ya were gbeyin ni,Oruko ti o sope ohun ko fe gbo, lo tun pada wa woo san, leyin ti enikan ti o wa nipa ti Olorun tu asiri ogun naa lo je ki o rorun lati tete se itusile fun ninu ogun naa, leyin eyi lo sese wa se alakoso daadaa, atipe obinrin ojo yen ti won daduro wa bere ise re pada leye -o-soka, ibi ti a maa nfojusi nigba miran ona kin sa ba maa n gbabe lo, E mo eyi daju pe E le se eniyan dudu loore ki o je wipe eniyan pupa ni Olorun yio so fun pe ki o lo san ore naa tabi kio je eniyan alawofun fun, Sugbon loni eniyan ti a ba se loore ni a o maa reti ki o san fun wa pada, mo fe ki e mo daju pe ko sebun ofe lodo Esu, ti Esu ba fun o ni ebun kan yio fe gba mewa dipo re tabi ogun. nigbati o ba gba mewa dipo eyo kan iwo yio tun fi tayo-tayo dupe lowo re pe o see pupo. E je ki a tun pada si die ninu awon ona ti egun ngba wonu aye eniyan. (1) Egun lati odo Olorun, Deuteronomy 27:15; Bibeli wipe “Egun ni fun Okunrin naa ti o ya ere gbigbe tabi dida, irira si Oluwa,ise owo onisona,tio si gbe e kale ni ikoko, gbogbo eniyan yio si dahun wipe Amin” Leyin eyi Olorun tun fi ejo ti o tan awon eniyan je ninu ogba Edeni bu “Olorun si wi fun ejo naa pe, nitori ti iwo ti se eyi, a fi o bu ninu gbogbo eran ati ninu gbogbo eranko igbe, inu re ni iwo o fi ma wo, erupe ile ni iwo o maa je li ojo aye re gbogbo Genesis3:4”. E gbo eyi ti Olorun so fun Kaini ti o pa arakunrin re{Abeli} “Nje nisisiyi a o fi o re lori ile, ti o yanu re gba eje arakunrin re lowo re”Genesis4:11. (2)Egun lati odo Obi si Omo, E je katun se agbeyewo eleyi ninu Bib- eli,Deut 27:16-26. “Egun ni fun eniti ko fi ba- ba re tabi iya re pe,gbogbo eniyan yio si dah- un wipe Amin.... ”. Noa gan fi omo re sepe nitori pe o ri ihoho re ti ko si le daso-boo o si wipe“Egbe ni fun Kenaani iranse ni yio ma se fun awon arakunrin re” Gen 9:25. (3)Egun lati odo iranse Olorun, E je katun yiri koko yi wo, Olorun maa n gbenu awon iranse re soro tabi lati enu eniyan re tabi ohunkohun ti Olorun ba fe lo “Josua si gegun li akoko naa wipe egun ni fun okunrin naa niwaju Oluwa ti yio dide, ti yio siko ilu Jeriko yi: pelu iku abi- keyin re ni yio fi gbe ilekun ibode re ro”Josua 6: 26. ninu iwe awon Oba kini1 6:34, ni oro yi ti se “Hieli ara Beteli ni o pe oro Olorun ni eke, eyiti o mu ki o ko Jeriko bi o se bere re ni akobi re Abiramu ku, nigbati o gbe ilekun re ro ni abikeyin re Segubu ku gegebi oro Oluwa ti o ti ipa Josua omo Nuni so”.(4) Egun idile, egun eyi tun je ogun ti o saba maa n ja eniyan gan, o maa nso eniyan di alaimose, alainilari, alabuku larin egbe tabi ogba. Idile miran Egun ti won ni were, ajogun ba tiwon niyen, osi ni telomiran, aikintojo ni telomiran, aisan oniruru nitelomiran, aikingbe nkan rere se nitelomiran,ati beebee lo, iru egun wo lo nja o tabi iru ogun wo lo n la koja bayi, boya airomo bi ni ogun ti o n la koja, ainise lowo, airalanu, ijakule lenu ise ni telomiran, bayi mo fe ki o pe Jesu sinu aye re ki o ba o dasi isoro naa tabi ki o ba o ba egun naa je patapata . Se e ko gbagbe pe Jesu ba iji wi lojo wonni ninu oko oju omi{Mathew 8:26}. Boya awon isoro wonyi tile je ki oro aye re su O tabi O tile ti re o ninu Emi lati je ki o tesiwaju. Mo gbaladura pe Olorun mi yio pase itura sinu aye re, idakeroro yio si ba gbogbo ogun tabi egun naa ti o n ja o loruko Jesu{AMIN}. Bibeli tile so fun wa nipa ona meji ti o wa , ona gboo-ro[Esu] ati ona too-ro[JESU], se e ko gbagbe pe ona gbooro lo lo sibi iparun ayeraye,ona tooro lo lo sibi iye ayeraye. Bayi ronu ara re eyi ti o fe mu ninu ona mejeji, Sugbon mo ro o ki o yan ona ti Jesu ki o baa le ni isinmi ayeraye leyin ohun gbo- gbo, mo gbaa ladura lekan sii pe, Olorun yio gbawa kuro lowo ise okunkun gbogbo [Amin]. Fun alaye sii, Ibere, Amoran, Ebe adura, Eri Yin tabi E n fe iwe yi sii, kowe si :-
ReviveThe Whole World For Christ.
P.O.Box 1736,
Osogbo, Osun State. Nigeria.
EWU FIFI ASIKO DOLA (PROCRASTNATION).
“Loti si jade, o si so fun awon ana re okunrin, ti nwon gbe awon omobirin re ni iyawo, o wipe, e dide, e jade kuro nihinyi; nitori Oluwa yio run ilu yi. Sugbon o dabi eletan loju awon ana re. Nigbati oye si nla, nigbana li awon angeli na le loti ni ire wipe,dide, mu aya re, ati awon omo- birin re mejeji ti owa nihin; ki iwo kio ma barun ninu ese ilu yi. Nigbati o si nlora, awon okunrin na nawo muu li owo, ati owo aya re ati owoomo birin re mejeji; Oluwa sa sanu fun u ! nwon si mu u jade, nwon si fii sehin odi ilu na”. (Genesis 19:14 -16).“Nigbati o si nlora.....”v 16; Ti a ko ba ni fepo boyo, o gbo oro Olorun nipase an- geli Olorun pe idajo Olorun nbo ati pe a o pa awon ilu yi run (Sodomu ati Gomorah). Ki se pe Loti gbo oro wonyi nikan, Otun gbaagbo, O tun so fun elomiran. O wa so fun awon ana re pe “ E dide, E jade kuro nihinyi, nitoriti Oluwa yio run ilu yi”. Sugbon ohun ti o bani lokanje ni wipe, lehin ti Loti ti gbo gbogbo nkan wonyi pe idajo nbo lori ilu wonni ti o si tun n lora. Ti o ba je wi pe o seese ki a pe eniyan jade ninu Orun Apadi (Hell) ki won maa bi enikokan pe, ngbo? ki lode ti iwo fi wa lorun apadi tabi iwo ko mo ona-igba -la ni? Mo mo daju pe opolopo ni yio so pe nko ni anfani ati mo ona igbala ni. Sugbon opolopo ni yio so pe, beeni mo mo nipa ona igbala , nko ya si ni. Nje o ni lokan lati lo si Orun Rere bi? Beeni, mofe lo si Orun Rere; Nitoripe won ti so fun mi tele pe Olorun yio won (weight)ise bubu- ru ti mo ti se, yio si tun won ise rere ti mo ti se, sugbon ti ise rere ba poju buburu lo Yio ju mi si Orun Rere, nitoripe ki se pataki lati gba Jesu loluwa ati Olugbala mi. Je kin so fun o eko eke leleyi je o!Mase tele iru eko odi bee. Elomiran yio wipe laipe emi naa yio gba Jesu loluwa ati Olugbala mi. Sugbon je kin so fun o fifi asi- ko dola o lewu pupo. Mo mo daju wipe gbogbo awon ti won wa lorun Apadi ko niwon yan lati lo sibe, sugbon opolopo loje wipe O gbo nipa Jesu Kristi, sugbon ti o gba wipe asiko ko i ti to ti ohun maa faye ohun fun un, sugbon lojiji ijamba kan sele yala ninu oko (motor) tabi ni ibomiran ti iku de lojiji ti ko sisi aye lati ronu- piwada tabi jewo ese ti o ti se, ni ireti lati yipa- da patapata tabi lati di omo Olorun ki o le ma reti ijoba Olorun fun okan re.Mofe ki awon eni- yan mo daju pe Bibeli wa, atipe Bibeli yi gan ni oro Olorun, ki awon eniyan mope Orun Apadi (HELL) wa nitooto ati pe Orun Rere naa wa nitooto gege bi iwe mimo Bibeli ti so fun wa. Gbogbo eniyan ti o ba ku lai ni Olugbala [Jesu Kristi] ninu aye won, won yio yoju si Orun Apadi. Awon ti won jewo Jesu loluwa won ki iku to de, won yio lo si Orun Rere. Bibeli je kio di mimo fun wa pe awon tio wa laye a o pa won larada,1Cor.15:51-58. Mofe ki o mo pe Olorun feran re,O si ti la ona abayoo fun o, lati ni igba- la, Olorun fe ki gbogbo eniyan di eni igbala, sugbon je ki nfi otito yi kun wipe, ti gbogbo eniyan ba ko lati gba ihinrere tabi ko Olorun sile, eleyi ko le yi Olorun pada ni ipo re, ki o O sope Ohun ko je Olorun mo.Curtis Hut son wipe “je ki a so fun gbogbo eniyan pe won gbodo ni igbala, sugbon won fe igbala kise low- olowo yi, ki won duro die si”. Je ki nso fun o pe lowolowo ti o nka iwe mi yi ni o gbodo wa Olu- gbala la wa ri ninu okan re tabi ki o to eniyan Olorun lo fun eko si lati gba Jesu loluwa ati Olu gbala re.R.A. Torrey wipe “Ologbon eniyan ni gbati o ba ri nkan ti o ye kio se ki o tete see ki o tete see lesekese,Sugbon omugo eniyan nigbati o ba ri nkan ti o ye ki o se, yio so pe O dara nitooto lati se,Sugbon nko ni se bayi, ma duro die si. Ta lo le so nkan ti o maa sele ni iseju kan si asiko yi, ju gbogbo re lo, ko si iru iku ti ko le pa eniyan yala iku Afowororiku, iku ijamba oko ofurufu tabi ti ile, tabi iku jijonamole ati beebee lo {e.t.c} Sugbon gba Jesu loluwa re ki iku to de ba o tabi igbasoke. “Nigbati O nlora..... ..” Kin se ewu sise okan le nikan ni o wa, Ewu ki eniyan padanu emi re na wa o, eniyan je alaye okan, Jesu wipe “Nitoripe ere kini fun eniyan,bi o jere gbogbo aye, ti o si so emi re nu”{marku 8:36} Ti o ba jere gbogbo aye ti o je eniti oni gbogbo nkan aye yi {moto,owo, ile,ile(land, house)omo} Ti o ba wa padanu emi re, iwo gan ni alaga iya tosi [idiotic bargain]. Eniyan ni Ori-rere,Sugbon esu ati awon omo ogun re lo so ti elomiran di Ori-buruku, Ori-rere yi ni a maa n gbe kiri elomiran yio gbe tire loju sodo[drop it at river side],elomiran yio ju tire sinu afefe, elomiran yio gbe tire fun oko,iyawo tabi omo re. Je kin so otito yi fun yin pe enikan ti o ba n fi igbala okan re sere ni oga awon Omugo, tabi ki eniyan maa so pe ko si aye fun Jesu ninu okan re lojojumo. Kin se ewu ki eniyan padanu emi re nikan ni o wa, Ewu ki eniyan lo si Orun apadi naa wa o,boya iwo ko tile ka si ewu rara, ki eniyan fi nkan ti o dara sile ki o si lo mu eyi ti ko dara. Je kin se apere kan fun yin, eniti o ni Emi-mimo ninu re ti o yan eniti koni lore kori- kosun, O n fi ara re sere niyen ! Je kin so bayi pe Ebun-Emimimo tabi Eso-emi dabi boolu felele[ball] ti eniyan lo n gba nibi ti iso yi kaka- kiri[nails] se e mo pe o ye kio o ronu ara re jinle ki o to maa gba iru boolu yi, tori wipe ti o ba sesi gun iso yio jo ni, wayio yio tun maa gbiyan ju lati fee pada bi o ti wa tele ri. Mo roo kio mase dara re po pelu egbe-okuku niwon igbati o ba jewo JESU loluwa re, dipo eyi, o ye ki o ba won wi ni[iwe Efesu 5:11]. Se e ko gbagbe pe Ewu nla ni ki eniyan lo si Orun-Apaadi, Eyin le ma fe gbo eyi, sugbon o ti di dandan lati soo fun yin. Orun apadi daju O !, eyi ti a n pe ni ina-ajo-iku[burning-hell]niwon igbati eniyan ba ku lai ni JESU,otito ni eyi pe orun apadi n duro dee, se iwo fee lo sibe ni tire?.Okunrin Oloro nii ku asi sin ati ni orun apadi O gboju re soke ninu opo-lopo iya [luku 16:22-23]. Je kin so fun yin Orun apadi je ibi ijiya-ayeraye,o je ibi ainireti rara, o je ibiti a kin dagbere fun Baba, Iya, Egbon, Aburo ati Ore pe odigbose. Orun Apadi je ibiti ko si ona-abayo. Nitorina Agbodo gbiyanju lati yera fun orun-apadi, kin se ibi ti o ye ki iwo ati emi lo. Je kin tun se apere miran fun wa, ka gba wipe nibiti a wa bayi Ki enikan wa so fun wa pe bombu wa ni be {bomb}ti o si ti setan ati bu jade nigbakugba si asiko ti a wa yi. E je kin bere pe,Tani ninu wa ti yio duro ki o bu loju wa?tabi tani yio duro lati se ohun kan tabi omiran ti ko ni wa ona abayo lati sa asala fun emi re?. Eyi nso fun wa nipa ipadabo Jesu leekeji, o je ewu nla fun awon ti ko gbaagbo.O tun je AYO fun awon ti o wa ninu re, mo roo ki o gba JESU yi loni, ki o ye fi asiko re dola. Fi ara re han JESU nipa jijewo ese re lai fikan pamo nibe fun OLUGBALA re, gbogbo ese ti o ti jewo yen ki o koo sile patapata, ki o pee sinu Okan re {JESU}, ki o gbaa tokantokan sinu aye re , ki o si tun setan lati le maa lo si ile ijosin ti o ba sunmo ile re tabi ibi ti won tin soro OLORUN ti o ye kooro “Nitori o wipe emi ti gbohun re li akoko itewogba,ati li ojo igbala ni mo si ti ran o lowo: kiyesii, nisisiyi ni akoko itewogba; kiyesii, nisisiyi ni ojo igbala” 2Korinti 6:2. Oni yi gan ni akoko igbala tire mase fi asiko dola mo. Mo eyi daju pe ti iku ba lo ka o mo kosi aye ironupiwada leyin iku,fi ti okunrin Oloro ni ati ti Lasaru se Odinwon aye re. Sugbon ranti pe OLA LE PE JU FUN O o.
Fun alaye sii, ibere,amoran,ebe adura, Eri Yin,tabi e n fe iwe yi sii kowe si :-
ReviveThe Whole World For Christ.
P.O.Box 1736,
Osogbo, Osun State. Nigeria.
GSM :08038352637 ;08060885544.
TI OLORUN BA FI SI O LO KAN LATI RAN ILE-ISE IWE YI LOWO SEE LONI OLA LEE PE JU, KOSI IYE OWO TI O KERE JU LATI FI SILE TABI TI O POJU, KI ORO OLORUN LE MAA GBINLE SII.
STIR UP THE GIFT OF GOD.
"Wherefore I put thee in remembrance that thou stir up the gift of God, which is in thee by the putting on of my hands. for God hath not given us the Spirit of fear, but of power, and of love and of a sound mind; be not thou therefore ashamed of the testimony of our Lord, nor of me his prisoner: but be thou
partaker of the affiliations of the gospel according to the power of God: who hath saved us, and called us with an holy calling to his own purpose and grace, which was given us in Christ Jesus before the world began, But is now made manifest by the appearing of our saviour Jesus Christ, who hath abolished death,
and hath brought life and immorality to light through the gospel: whereunto I am appointed a preacher and an apostle, and a teacher of the gentiles. For the which cause I also suffer these things: Nevertheless am persuaded that he is able to keep that which I have committed unto him against that day.
Hold fast the form of sound words, which thou hast heard of me, in faith and love which is in Christ Jesus" Verses 6-13. I emphasize on verse 6 "Wherefore I put thee in remembrance that thou stir up the gift of God, which is in thee by the putting on of my hands" Paul, writing to young Timothy, saying, Timothy, you have been saved. Timothy, you have the Holy Spirit dwelling in you, God has called you into His service, I place my hands upon you as a token of God's call. Now Timothy stir yourself up and do what God asks of you, Here is a picture
of a fundamentalist by the name of Paul writting to a young fundamentalist preacher by the name of Timothy. Both believed the word of God, believed in God or Christ, and were saved and called of God. Paul was seeking to stir up this young man. In first &second Timothy he kept on exhorting him, “Endure
hardship as a good soldier … Study to shew thyself approved" What was he doing? The very thing we have to do. If we don't stir up people, move people, we have failed, if you can preach on Sunday morning, Sunday night and all the rest of days and no one is stirred to go out and do what God says then you
haven't done much. Paul was doing this at all time. He wrote to the Christian in the church at Rome, at Corinth, at Philippi, at Ephesus, in the same manner- to stir and move and shake them. People don't want to be shaken;they would rather sit still. They want to come to church every time and listen to you for an hour, get up and walk out the door, go home and eat dinner, and forget about what God asked we must stir people either they like it or not. Moses had that in his mind when he said, “beware, lest thou forget the Lord" Deuteronomy 6:12. He was stirring them up and we must do the same. Today fundamentalists need to be stirred. There are things that ought to stir us. We ought to be scared by sin. This is a Wicked day, Immoral day, Loose day,
Dirty day, Radio, Television, Magazine, Books, most of thing is turning people away from God. The sin of this day is deception. It is a day of shadows and that should trouble us all. Some people just don't seem to get bothered. They go on their way, well, the child of God should be stirred to a holy compassion, a condemnation of Sin an acknowledgement of what he believes in his own heart. The indifference of this day should stir us. Paul said, “For all seek their own not the things which are Jesus Christ" Philippians 2:21. We are not concerned, we see selfishness on every hand. People don't want to be stirred They have gotten in a rut. A rut is a grave with both ends knocked out. Do we pray "O GOD, stir my heart, O God, Move me? O God let me be what you want me to be" O Father, stir us onto Repentance, Here is the word of God " Now I rejoice, not that ye were made sorry, but that ye sorrowed to repentance: for ye were made sorry after a godly manner, that ye might receive damage by us in nothing, 2corinthians 7:9. We put
emphasis on worldly things, but we are not putting emphasis on the things of God, on the salvation of souls and on winning people to the Lord. Instead, we have thought of money {power to get wealth} possessions and buildings.e.t.c.Christians need to be stirred to repentance. "If we confess our sins, he is faithful and just to forgive us our sins and to cleanse us from all
unrightteousness"1john 1:9. Confess the Coldness of our hearts, our critical Spirits, our lazy, lukewarm attitudes. Confess the sins of commission and the sins of omission, There is another prayer "O Father, stir us to return to the basics. Do you know that seventy-five percent {75%} of the people in our Churches today have never read through the Bible? They have read most of it,
most especially Psalm. But not all of it. Stir us to Revival "O Lord, revive thy work in the midst of the years" Habakkuk 3:2. I have seen revival in Churches, I mean, sweeping revivals. Souls were saved, hearts were touched, and altars were filled. I have seen the hand of God at work. O God, stir us to repent of things, things that are wrong: things that are doubtful: things that mean nothing in our Lives: Get rid of that which is going to hinder and ask the Lord to make your heart right. Let us return to the basic things of the word of God, Prayer, Soul winning and revival. Let us pray, O GOD send a revival, let it begin in me. Finally brethren, keep your heart stirred up, keep your emotions stirred, Hate sin, Love Christ, Love souls, Love the word of God, Preach the Gospel and Seek the Salvation of Others, God of Peace will be with you all {AMEN}.
Let us hear your Testimony.
IF THE LORD PUT IT IN YOUR MIND THAT YOU SHOULD JOIN THIS TRACT MINISTRY, OR SUPPORT THIS TRACT MINISTRY, DO IT TODAY TOMMOROW MAY BE TOO LATE. NO AMOUNT OF MONEY THAT TOO SMALL TO SUPPORT. THANK'S GOD BLESS.
"FOR THEY SAY, BUT DO NOT" MATHEW 23:1- 33.
"But do not be after their works: for they say, but do not" Mathew 23:3. This people abound in the church today, in the street, in the market, in every part of the world. This is hypocrisy and this is the reason why all teachings we receive do not reflect in the lives of believers. They call themselves Jews but in reality they are the synagogues of Satan, in doctrine they can teach well, but they fail to put it into practice. The time has come the spirit of Ezra in our churches "For Ezra had prepared his heart to seek the law of the Lord and to do it and to teach in Israel statues and judgements" {Ezra 7:10}. Examine this truth As a Leader and follower, Disciple or Nominal Christian and change your life. Let us be examples to the unbelievers let our lives agree with andbe in line with our preaching. The Bible says " in all things show yourself as an example of good works, in doctrine show forth uncorrupts". Apostle Paul heard about false teachers, he now instruct Titus about faith, Conduct and warnings about false teachers he should " teach what is in accord with sound doctrine. Teach the older men to be temperate, worthy of respect, self-controlled and sound in faith, in love and in endurance. Likewise, teach the older women not to be slanderers or addicted too much wine but to teach what is good. Then they can train the younger women to love their husbands and children, to be self-controlled and pure, to be busy at home, to be kind, and to be subject to their husbands, so that no one will malign the word of God. Similarly, encouragement the young men to be self-controlled, in everything set them an example by doing what is good. In your teaching show integrity, seriousness and soundness of speech that can not be condemned, so that those who oppose you may be ashamed because they have nothing bad to say about us"Titus 2:1-8. Today nominal Christian are numerous in the World, "Jesus said to the crowd and to his disciples: The teachers of the law and the Pharisees sit in Moses seat, so you must obey them and do not do what they do, for they do not practice what they preach. They tie up heavy loads and put them on men's shoulder, but they themselves are not willing to lift a finger to move them" Mathew 23:1-4; Today people like the big position in the society. Their faith is to seek for position "Everything they do is done for men to see… They love the place of honor at banquets and the most important seats in the
synagugues, They love to be greeted in the market places and to have men call them 'Rabbi' or Teacher ". With all these things God desires humility "And do not call any one on earth father for you have one father and is in heaven.nor are you to be called teacher, for you have one teacher, the Christ. The greatest among you will be your servant, for whoever exalts himself will be humble, and whoever humbles himself will be exalted" Verses 5-12. Due to this Jesus rebuked the life of hypocrisy "Woe to you teachers of the law and Pharisees, you hypocrisy, you shut the kingdom of heaven in Men's faces. You yourselves do not enter, nor will you let those who are trying to enter. Let me assure you that this sects of people they were obstacles for those who are ready to receive the gospel of Christ, They even know how to set good doctrine and they will not follow it, Jesus curse them "woe to you, blind guides, you say, if anyone swears by the temple, it means nothing; but if anyone swears by the gold of the temple, he is bound by his oath, you blind fools which is greater, the gold or the temple that makes the gold sacred." Verses 13-24. Are you in the group of self-righteousness people? "Woe to you teachers of the law and Pharisees, you hypocrites you clean the
outside of the cup and dish, but inside they are full of greed and self-indulgence, blind Pharisees! First clean the inside of the cup and dish, and then the outside also will be clean, woe to you teachers of the law and Pharisees, you hypocrites! You are like white washed tombs, which look beautiful on the outside but on the inside are full of dead men's bones and everything unclean, in the same way on the outside you appear o people as righteous but on the inside you are full of hypocrisy and wickedness". Verses25-33. Sound doctrine good, but doctrine that not in accord with God's word can kill. Also the spirit of God always gives life abundant. Therefore surrender yourself to the spirit of God that enlightens us on how to be doers of the word of God. Do not be silent because of fear inability to do. Say it and do it, the God of peace will be with you. Finally whatever is True, whatever is Noble, whatever is Right, whatever is ever Pure, whatever is Lovely, whatever is Admirable, if anything is Excellent or Praise worthy - think about such
things. Whatever you have learned, received or heard from me or seen in me put it into practice and the God of peace will be with you.{AMEN}Philippians 4:8-9.
Let us hear your Testimony.
IF THE LORD PUT IT IN YOUR MIND THAT YOU SHOULD JOIN THIS TRACT MINISTRY, OR SUPPORT THIS TRACT MINISTRY, DO IT TODAY TOMMOROW MAY BE TOO LATE. NO AMOUNT OF MONEY THAT TOO SMALL TO SUPPORT. THANK'S GOD BLESS.
Subscribe to:
Posts (Atom)